Oração à Ifá

Yorubá


1. Iba Olodumaré
Iba Orunmila Baba Agbonmiregun
Iba Okanlenirinwo Irunmole
Iba Akoda
5. Iba Aseda
Iba Oringun mereerin ayê
Iba Ile Ogeere afoko yeri
Iba atiyo Ojo
Iba Atiwo Oorun
10. Iba Ikorita meta ipade Orum
Iba F’olojo oni
Iba Eegun Ile
Iba Oosa Oja
Iba Agba
15. Iba Omode
Iba Oturarera tii se Alaabo Ijo Orunmila Ato
Iba Osalogbe ti o bi Egbe Odo Orunmila
Awa Egbe Odo Orunmila juba O, Ki iba wa se
T’omode ba juba baba re, agbe’le aye pe
20. Ada se nii hum omo
Iba kii hum omo eniyan
Isu sisun kii hum iná
Akoogba kii hum oloko
Atipa kii hum oku
25. Aso funfun kii hum olorisa
Eni ni nhum ogbon
Agbon kii hum’ni
Bi ekolo ba juba ile ile a lanu fun
Eyin araiye, E je o ju waa se o
30. Ka’ma ku lomode
Ka’ma dagba atoro je
Kaye o – ye wa o
Ka riba ti se
Ka rona gbe gba
35. Ka’ma r’ija Omo araye O
Ka’ma r’ija eleye O
A juba O! A juba O!! A juba O!!!
Ki iba wa ma hum wa O
Ase